AFE 130 - YORUBA LANGUAGE
AWON ORIN TI A KO
1. Orin ole
Ole alapa masise,
Ole daso iya bora sun,
Eni f’ole ole roko fe, ewa waye ole o, ole alapa masise sio.
2. Orin eya ara
Orimi, ejika, orokun, ese
Orimi, ejika, orokun, ese
Orimi, ejika, orokun, ese
Tire ni Oluwa patapata.
3. Orin awon omo alaigboran
Awon omo alaigboran po nile iwe
Won ko feti sile soun toluko kowon
Boluko ni kan kawe
Won a si ma sere ka
Won a jeun, jeun, jeun
Won a gbodo roboto
Ise, ise iyen kii se tiwon
Ere, ere iyen sani tiwon
Dodo ati raisi kogbodo koja
Won a jeun, jeun, jeun
Won gbodo roboto.
4. Orin eyo
Eyo o, aiye le eyo o
Eyo o, aiye le eyo o
Eyo baba tawa to nfi goolu sere
Awa o ni sanwo olubode
Odile
Ki na tun gbe? Owo, owo na tungbe
Ki na fi se? Aso, aso na fira
Aso kina ra? Aso eye oyinbo
Eni jaale, eni jaale a re ewon o
Eh eh eh eh oloba, eh eh oloba
Oloba mijo aya re miwo
Oloba mi jo se bi oba, eh eh oloba
Asa o eh, eye gbeyefo
Asa o eh ah, eye gbeyefo
Igunugun eye o eh, eye o eh
Aluko eye osa, eye osa
Oloba mijo aya re miwo
Oloba mijo se bi oba, eh eh oloba o eh.
5. Orin ojo/osu
Ogbon ojo ni september, april, june and november
February nikan ni 28…..
Awon yoku lekan logbon ojo.
6. Days of the week
Aiku - Sunday
Aje - Monday
Isegun - Tuesday
Ojoru - Wednesday
Ojobo - Thursday
Eti - Friday
Abameta - Saturday
7. Months of the year
seere - January
Erele - February
Erena - March
Igbe - April
Ebibi - May
Okudu - june
Agemo - July
Ogun - August
Owewe - September
Owara - October
Bellu - November
Ope - December
Translations of some words in yoruba
Three storey building - Ile alaja meta
Two storey building - Ile alaja meji
One storey building - Ile alaja kan
Bungalow - Ile ile
Church - Ile ijosin/ soosi
Mosque - Mosalasi
Higher institution - Ile eko giga
School - Ile iwe
Bank - Ile ifowo pamo
Hall - Gbongan
Court - Ile ejo
Shop - Ile itaja/soobu
Iya - Mother
Baba - Father
Okunrin - Boy/man
Obinrin - Girl/woman
Aburo - Younger siblings
Egbon - Elder silbings
Omode - Child/infant
Iya-iya - Maternal grandmother
Baba-baba -paternal grandfather
Kini? - What?
Kibo? - Where?
ALIPHABEETI YORUBA
Aa - Aja dog
Ba - Bata drum
Dd -Doje circle knife
Ee - Ejo snake
Ee - Eye bird
Ff - Fila cap
Gg - Gele head gear
GB gb - Gbaguda cassava
Ii - igi tree
Hh - Hausa hausa
Jj - Jagunjagun warrior
Kk - Kiniun lion
Ll - labalaba butterfly
Mm - Maalu cow
Nn - Nagudu clay pot
Oo - ogongo Ostrich
Oo - Ogede banana
Pp -Pepeye duck
Rr - Rakunmi camel
Ss - Salubata slippers
Ss - saago jug
Tt - Tafatafa arrow shooter
Uu - Uku-uku kind of intoxicating drink
Ww - Wahala trouble
Yy - Yanmuyanmu mosquito