YORUBA LANGAUGE SCHEME OF WORK
BASIC 7 SAA KEJI
OSE AKOONU ISE
1. Agbeyewo Awon koko Ise Taamu To Koja
2. Alifabeeti yoruba
3. Awon ohun ti a le ri ninu ile iwe
4. IDAMO: Oruko awon kan lawujo; nipa ise (ode, babalawo,
alagbede, abbl), nipa ipo; (otun, iyalode, baale, oba, abbl)
5. Ayoka kukuru
6. Girama Yoruba; oro – ise ninu gbolohun. Bi a se le da oro ise
mo ninu gbolohun.
7. Oruko awon eso ati igi: Afihan awon eso bi osan,ogede,oro,
ibepe,abbl.
8. Oro oruko: oruko awon eranko.
9. Asa ati isesi Yoruba – awon orin keekeekee ati ere idaraya omode.
10. ATUNYEWO si awon koko ise fun saa yii.
11. IDANWO.
WEEK TWO (Ò̩SÈ̩ KEJÌ)
TOPIC: ALIFABETI YORUBA
Ninu ede yoruba, awon wonyi ni alufabeeti ti a ni, won si je meedogbon
(25). Awon ni
ALIFABEETI NLA
A B D E E F G GB H I J
K L M N O O P R S S T
U W Y
Alifabeeti kekere
a b d e e f g gb h i j
k l m n o o p r s s t
u w y
Alifabeeti Yoruba pin si ipa meji akoko ni iro konsonanti, ekeji ni iro
faweli.
1. Iro Konsonanti Yoruba
B D F G GB H J K L M N
P R S S T W Y
2. Iro Faweli Yoruba ( A E E I O O U)
A le pin faweli Yoruba si ipa meji (1) Aranmupe (2) Airanmupe
1. Iro Faweli Aranmupe
An, En, In, On, Un
2. Iro Faweli Airanmupe
A, E, E, I, O, O, U
Igbelewon
Di awon aye ti o sofo ninu awon leta wonyi.
1. ______ ni konsonanti marun-un akoko.
2. A ____ ____ I _____ O _____
Ise Amurele
1. Iro konsonati meloo ni o wa ninu alifabeeti ede Yoruba?
2. Se akosile orisi iro faweli Yoruba
3. Se akosile faweli airanmupe
Ò̩SÈ̩ KÉ̩TÁ (WEEK THREE)
TOPIC: AWON OHUN TI A LE RI NINU ILE IWE
1. O̩gbà ilé ìwé = School compound
E̩fun- ìkò̩wé/s̩ó̩ò̩kì = Chalk
Ìdánwò = Examination
Yàrá ìkò̩wé = Class room
Ò̩gá ilé ìwé = Principal
Olùko̩ = Teacher
Aké̩kò̩ó̩ = Student
2. NǸKAN ÀYÍKÁ ILÉ- ÌWÉ
Ìwé ( Book) Bírò / Gègé (pen)
Pátákó- ìkò̩wé ( chalkboard) Bó̩ò̩lù (Ball)
Bó̩ò̩sì ilé-ìwé (school bus) Tábìlì (Table)
Àga(chair) Aago (clock)
Rúlà (Ruler) Agogo (bell)
IS̩É̩ S̩ÍS̩I ( WORK TO DO)
Write the Yoruba name of the following objects
(i) Tree (ii) House (iii) Cutlass (iv) Cup (v) Light
Ò̩S̩ E̩ KÉ̩RIN (WEEK FOUR)
TOPIC: IDAMO: Oruko awon kan lawujo; nipa ise (ode,
babalawo, alagbede, abbl), nipa ipo
IS̩É YORÙBÁ
YORUBA OCCUPATION
YORUBA ENGLISH
Àgbè̩ Farmer
O̩de̩ Hunter
Àyàn/ Onílù Drummer
Babaláwo Herbalist
Onísègùn Native doctor
Onkola Surgeon
Onidiri Hairdresser
Onigbajamo Barber
Ako̩pe̩ Palm wine tapper
Gbe̩nagbe̩na Carpenter
O̩mo̩le Bricklayer/ Builder
Alapata Butcher
Ahunso̩ Weaver
Onisowo Trader
Alagbe̩de̩ Blacksmith
Àgbè̩ ( Farmer)
IS̩É̩ S̩ÍS̩E (WOOK TO DO)
(1) What are the following words in Yoruba ?
(i) herbalist (ii) carpenter (iii) hunter (iv) farmer (v) driver
(2) Pronounce the following words
(i) ayan (ii) alagbe (iii) ona (iv) pe̩jape̩ja (v) alapata
Ò̩SÈ̩ KÁRÙN ÚN
TOPIC: AYOKA KUKURU
EWI APILEKO – MURA SI ISE (lati owo J.F. Odunjo)
Ise ni oogun ise
Mura si ise ore mi
Ise la fi i deni giga
Bi a ko ba reni fehinti
Bi ole laa ri
Bi a ko ba reni gbekele
A tera mo ise eni
Iya re le lowo lowo
Baba re si le lesin leekan
Bi o ba gboju le won
O te tan ni mo so fun o
Ohun ti a ko ba jiya fun
Se ki i le tojo
Ohun ti a ba fara sise fun
Ni i pe lowo eni
Apa lara, igunpa niye kan
Bi aye n fe o lowo
Bi o ba lowo lowo
Won a ma fe o lola
Tabi bi o wa nipo atata
Tabi bi o wa nipo atata
Aye a ye o si terin terin
Je ki o deni n raago
Ki o ri bi aye ti n yinmu si o
Eko sit un n soni doga
Mura ki o ko o daradara
Bi o ri opo eniyan ti won n feko sein rin
Iya n bo fomo ti ko gbon
Ekun n be fomo ti n sa kiri
Ma fowuro sere ore mi
Mura si ise ojo n lo
Awon akekoo yoo ka ewi yii ni akaye won o sit un gbiyanju lati ko o si
ori.
Igbelewon
1. Se alaye gbolohun yii bi o ti ye o si ‘Ise ni oogun ise’
2. Ki ni itumo oro yii ‘raago’
3. Ipenija wo ni o ri gba ninu ewi yii?
Ise Amurele
Gbiyanju lati ka ewi yii laiwo iwe.
Ò̩SÈ̩ KE̩ FA (WEEK SIX)
TOPIC: Girama Yoruba; oro – ise ninu gbolohun.
ISORI-ORO NINU GBOLOHUN
Isori or ni owo ti a pin awon oro inu ede kan si. Opolopo
akitiyan ni awon onimo girama Yoruba ode-oni ti se lati pin
awon oro inu gbolohun si isori. Isori oro mejo ni a ni ninu ede
Yoruba lowolowo bayii. Awon naa ni
(i) Oro-oruko ( Noun)
(ii) Oro-aropo oruko (pronouns)
(iii) Oro-ise (verb)
(iv) Oro-aponle (Adverb)
(v) Oro-apejuwe ( Adjective)
(vi) Oro-atokun (Preposition)
(vii) Oro-asopo ( Conjunction)
Oro-ISe
Oro-ise ni oro ti o n fi isele inu gbolohun han. O je opomulero fun
gbolohun ede Yoruba. O maa n fun gbolohun ni itumo̩. Bi apeere: lo, sun,
sare, jenu, se, wa, ri, han, ropo, duro, jooo, rerin-in, dide, korin, sunkun,
wo, ro, ka, pade, to, to, abbl.
Oro-Aponle
Oro ti a fi n pon oro-ise tabi apola-ise ninu gbolohun. Bi apeere: kiakia,
foo, werewere, taarata, fee, gbangba, regi, nini, booli, jaburata, rekete,
abbl.
Oro Apejuwe
Isori oro ti a fin se apejuwe ohun tabi eni kan. Bi apeere: pupa,
fuye, dudu, funfun, tobi, nla, kekere, kukuru, giga, sisanra, titin-in-ni,
pipon, dide, abbl.
(vii) Oro-Atokun
Oro ti o n fi ibasepo laarin awon akopa ninu gbolohun han. Bi
apeere: si, ni, fi ati ti.
IGBELEWON
Daruko awon isori oro to wa ninu ede Yoruba. Ko gbolohun kan fun isori
kan ki o si fa ila si idi oro to je ti isori naa. Gbolohun mejo ni
gbogbo re yoo je.
Ise Amurele
Se iwadii lori ise ti isori kookan n se ninu gbolohun.
Ò̩SÈ̩ KÉJE (WEEK SEVEN)
TOPIC: Oruko awon eso ati igi: Afihan awon eso bii osan,ogede abbl
(1) ORISIRISI ESO
Osan, Obi
Kasu, Awusa/ Asala
Mongoro, Epa
Goba, Ibe̩pe̩
O̩gede, Agbon
Agbalumo, orogbo
Igba, Ikan
O̩pe-oyinbo, Oro
(2) AFIHAN AWO̩N ESO
È̩SO ( Fruits)
Ope Oyinbo (Pineapple)
O̩san ( Orange)
Àgbálùmò̩ (white star apple)
Mó̩ńgóòrò ( Mango)
Àgbo̩n ( Coconut)
Ò̩gè̩dè̩ ( Banana)
Igbelewon
Daruko orisi ohun jije mewa to mo.
Ise Amurele
Se alaye ni sooki lori okan ninu gbigbo ounje wonyi.
1. Iresi
2. Eba
3. Isu
Ò̩SÈ̩ KÉ̩JO̩ (WEEK EIGHT)
TOPIC: ORO ORUKO: ORUKO AWON ERANKO
Oro Oruko (Noun)
Oro oruko ni oro ti o n so oruko ohun tabi eni kan, yala elemi tabi
alailemii, ohun ti a le ri dimu tabi eyi ti a ko le ri dimu, eyi to se e ka tabi
eyi ti ko se e ka. Bi apeere:
Oruko eniyan – Olu, Fausa, Joonu, Tunji, Sayo, abbl
Oruko eranko – ewure, aja, ekun, maluu, abbl
Oruko ilu – Ibadan, Eko, Ondo, Abeokuta, abbl
Oruko ohun aridimu – Okuta, iwe, ilkeun, aso, abbl
Oruko afoyemo – alaafia, ife, ibanuje, efori, abbl
ORISI ERANK TI O WA
1. Eranko ile (domestic animal) Awon wonyi ni eranko ti won n gbe
ile ti won ki n dede pani lara bi ko ba nidi. Apeere iru awon eranko
be ni ologbo, aja, ekute, obo, ewure abbl.
2. Eranko igbe (wild animal): Awon wonyi ni eranko ti won n gbe
inu igbo paapa inu igba kijikiji ti won si le se eniyan ni jamba.
Apeere iru awon eranko be ni ejo, kiniun, erin, efon, elede igan,
ikoko, kolokolo, inaki, ijimere, abbl.
3. Eranko – omi: Awon eranko kan wa ti won n gbe inu omi. Apeere
iru awon eranko be ni eja, oni, ijapa inu omi, erinmi, abbl.
Ologbo (Cat) Ajá (Dog)
Ewure̩ ( Goat) Ejò ( snake)
E̩sin ( Horse) Kiniun (Lion)
Eku( Rat)
ISE AMURELE
Daruko boya eye tabi eranko ni awon nkan wonyi ki o si so
ibugbe won pelu.
1. Akuko
2. Ikun
3. Aleegba
4. Igun
5. Opolo
6. Daruko orisi ejo marun to wa.
Ò̩SÈ̩ KÉ̩SÀN ÁN (WEEK NINE)
TOPIC: AWON ORIN KEEKEEKEE ATI ERE IDARAYA
OMODE
Children’s Songs and plays
ORIN O̩MO̩DE (Children song)
Ojò ń rò̩ (it is raining)
Ojo n ro It is raining
S̩ere ninu ile Play inside the house
Ma wo̩ ‘nu òjò Don’t enter rain
Kí as̩o̩ re̩ So that your cloth
Ma baa tutu Would not wet
Ki otutu So that cold
Ma ba mu o̩o̩ Would not catch you.
Bata re̩ a dun ko! Ko!! Ka!!!
Bata re̩ a dun ko! Ko!! Ka!!!
Bi o ba kawe re̩,
Bata re̩ a dun ko! Ko!! Ka!!!
ERE IDARAYA OMODE
(1) Lile Ckun mcran 2. Ta lo wa nu [va nqz
Eve M23 [m[ kekere kan ni
Lile O ko ri b[vo Xe ki n wa wa ma wa woo
Eve M12 8w[ lo pqz abbl.
Lile O k[run b[va 3. Bojuboju o
Eve M12 oloro n b[
Lile O fc l[ xe ki n xi abbl
Eve M12 abbl.
*velew[n : Ki aw[n ak1k-= orin erem[de ati orin
ak[niniwa meji meji
Ò̩SÈ̩ KÉ̩WÀÁ (WEEK TEN)
ATUNYEWO AWON KOKO ISE TAAMU YII ( Revision)
Ò̩SÈ̩ KÓ̩kànlàá (WEEK ELEVEN)
IDANWO (Examination)