PRAYER POINTS
Scriptural Text: And it came to pass, when men began to multiply on the face of the earth, and
daughters were born unto them, that the sons of God saw the daughters of men that they were
fair and they took them wives of all which they chose. Genesis 6:1-2
PRAYER POINTS:
1. Blood of Jesus Christ, begin to plead for me.
2. Mercy of the Lord, appear in my foundations, in the name of Jesus Christ.
3. Ancestral evil dedication of the offspring of my father's house,by the blood of Jesus Christ and
fire, break and release me.
4. Ancestral evil dedication of the offspring of my mother's house,by the blood of Jesus Christ
and fire, break and release me.
5. Ancestral evil covenants binding on the offspring of my father's house, by the blood of Jesus
Christ and fire, break and release me.
6. Ancestral evil covenant binding on the offspring of my mother's house, by the blood of Jesus
Christ and fire, break and release me.
7.Inherited bondage through spirit marriage, be neutralized by the blood of Jesus Christ, break by
fire.
8.I file a divorce at the court of heaven against spirit wife and spirit 9.husband in the name of
Jesus Christ.
9.spirit husband,spirit wife, I renounce you by the blood of Jesus life binding to spirit wife and
spirit husband, by the blood of Jesus Christ,Irenounce you, break.
11. Foundational evil dedication in my life binding to spirit wife and spirit husband, by the blood
of Jesus Christ, I renounce you,break by fire.
12. Evil covenants signed in error with the spirit husband and spirit wife, by the blood of Jesus
Christ, break and release me now.
13. Evil covenants, signed through sins, with spirit husband and spirit wife, by the blood of Jesus
Christ, break and release me now.
14. Spirit husband,spirit wife, I divorce you by the blood of Jesus.
15. Wedding rings, wedding dress, other wedding apparels from spirit husband and wife, I pull
you off, in the name of Jesus Christ.[Demonstrate this]
16. Wedding rings, wedding dress, other wedding apparels from spirit husband and wife, catch
fire and burn to ashes in the name of Jesus Christ.
17. Marriage certificates and pictures with spirit husband and wife,catch fire in the name of Jesus
Christ.
18. Property of the spirit husband and spirit wife in my possession,catch fire, burn to ashes, in
the name of Jesus Christ.
19. Deposits of the spirit husband and spirit wife in my blood, bones,Water and flesh, come out
by fire, in the name of Jesus.
20. Deposits of the spirit husband and spirit wife in my womb, I shake you out by fire, in the
name of Jesus.
21. Legal hold of the spirit husband and spirit wife upon my life,break by fire in the name of
Jesus Christ.
22. Every power that is working against my earthly marriage, fall down and die, in the name of
Jesus.
23. Spirit children, I renounce you, die by fire, in the name of Jesus Christ.
24. I recover by fire, every of my belongings in the custody of spirit wives and spirit husbands in
the name of Jesus Christ.
25. I renounce and reject the name given to me by the spirit husband or wife, in the name of
Jesus. 26. My blood, sperm, my saliva or any other part of my body on the altars of the spirit
husband or wife, catch fire in the name of Jesus Christ.
27. Special announcement to the kingdom of darkness and to spirit husband and spirit wife, hear
me and hear me well, Jesus is my husband.
28. Influences and control of the spirit husband or wife on my life and home, break by fire in the
name of Jesus.
29. You spirit husband or wife, distressing my life and earthly marriage I bind you with hot
chains and fetters of God in the name of Jesus Christ, in the name of Jesus.
30. Curses, evil pronouncements, spell, jinx, enchantments and incantations placed upon me by
the spirit husband or wife, break by the blood of Jesus Christ and fire in the name of Jesus.
Youruba.
IJEWO:
O si se nigbati eniyan bere sini po lori ile ti won si bi omo binrin, li awon omo Olorun ri awon
omo obinrin eniyan pe nwon lewa won fe aya fun ara won ninu gbogbo awon ti won yan.
KOKO ADURA
1. Eje Jesu bere sini bebe fun mi.
2.Aanu Oluwa, farahan niipile mi ni oruko Jesu.
3. Ifiji ibi ti awon omo ile baba mi, nipa eje Jesu ati ina ja ki o sit u mi sile.
4. Ifiji ibi ti iran ti awon omo ile iya mi nipa eje Jesu ati ina ja ki o si tumi sile.
5. Majemu ibi ti iran ti o de awon omo ile baba mi nipa eje Jesu ati ina ja ki o si tumi sile.
6. Majemu ibi ti iran ti o de awon omo ile iya mi nipa eje Jesu ati inaja ki o situ mi sile.
7. Ide ti mo jogun nipase igbeyawo temi, baje nipa eje Jesu Kristi,fo nipa ina.
8. Mo ko iwe ikosile si ile ejo torun lori aya orun ati oko orun ni oruko Jesu.
9.Oko orun aya orun, mo ko e nipa eje Jesu tumisile nipa ina.
10. Majemu buburu ipile to so aya orun ati oko orun po mo aye mi,nipa eje Jesu mo ko e fo.
11. Ifiji ibi ti ipile ninu aye mi to so aye mi po mo aya ati oko orun,mo ko e nipa eje Jesu ja.
12. Majemu buburu ti a fowosi nipase asise pelu oko orun ati aya orun, nipa eje Jesu ja ki o si
tumi sile.
13.Majemu buburu ti a fowosi nipase ese pelu oko orun ati aya orun, nipa eje Jesu ja ki o si tumi
sile.
14. Oko orun, aya orun mo ko e sile nipa eje Jesu.
15. Oruka igbeyawo, aso igbeyawo gbogbo awon nkan igbeyawo lati odo oko ati aya orun mo bo
yin danu ni oruko Jesu Kristi ( fi si oju ise)
16. Oruka igbeyawo,aso igbeyawo gbogbo awon nkan igbeyawo
Kristi.
Lati odo oko ati aya orun gbina kosi jona di eru ni oruko Jesu
Oruko Jesu.17. Iwe eri igbeyawo ati aworan pelu oko orun ati aya orun jona ni
18. Ohun ini oko orun ati aya orun to wa lowo mi jona ki o si di eru ni oruko Jesu.
19. Ifipamo oko ati aya orun ninu eje mi, egungun mi, omi ati ara jade nipa ina ni oruko Jesu.
Ni oruko Jesu.20. Ifipamo oko ati aya orun ni ile omo mi mo gbon e jade nipa ina
Jesu.21. Aye ofin ti oko orun ati aya orun fi mumi fo nipa ina ni oruko
Ni oruko Jesu.22. Gbogbo agbara to n sise lodi si igbeyawo mi taye, subu ki o ku
23. Eyin omo orun mo ko yin e ku nipa ina ni oruko Jesu.
Aya orun ni oruko Jesu.24. Mo gba pada nipa ina, gbogbo ohun ini mi lowo oko orun ati
25. Moko oruko ti oko orun tabi aya orun fun mi ni oruko Jesu.
26. Eje mi, ato mi, ito mi tabi eyikeyi ninu eya ara mi lori pepe oko tabi aya orun gbina ni oruko
Jesu.
27. Ikede Pataki si ijoba okunkun ati si oko orun ati aya orun, e gbo mi ki e tun gbomi dada, Jesu
ni oko mi.
Nipa ina ni oruko Jesu.28. Idari ati ase oko orun tabi aya orun lori aye mi ati idile mi, fo
29. Iwo oko orun ati aya orun to n damu aye mi ati igbeyawo miti Kristi.
30.Egun, oro ibi, epe, afose ati faiya ti oko orun tabi aya orun gbe lemi lori fo nipa eje Jesu
Kristi.