IMULE AWON AGBA*
Eku asin tutu 4
Epo obo
Egbo tude
Eso ido
Eso werenjeje
Eyin ororo 4
Atare nla 4
Ose dudu
Ewe ajeobale
Ewe origin
*Sise re*
Ao ko ifun inu opolo yen kuro
Ao fi epo obo sinu ikan ati eyin ororo kan
Ao fi egbo tude ati eyin ororo sinu eku asin keji
Ao fi eso ldo ati eyin ororo sinu eku asin keta
Ao fi werenjeje ati eyin ororo sinu eku asin kerin
Ao ko sinu agbada
Ao ko atare mererin sinu re
Ao da ewe ajeobale ati ewe orijin bomole
Ao wa jopo
Ao lo kuna dada
Ao mafi epo loo lalale
Ao wa tun gun ifun eku asin mererin ati epo obo yen papo
Ao mafi we ni ale ki a to malo ebu yen
: *IMULE GBOJU GBOYA*
Ori ako aja kan, ori abo aja kan, ewe tannaposo pupo, ewe abirikolo pupo, ewe ajeobale, epo obo,
epo igi nla, emu alakan mejeji, opolopo odidi atare, eyin ororo meta, ao koko se eyin naa ki ato ko
tele ape, so wa ko gbogbo eroja yen le lori, ao wa jo po, ti aba jo tan, ao ro sinu sere kan, ti aba fe
maa lo, ao bu die sinu ewe ogede agbagba, ao te ni ifa Irete meji le lori, ti aba pe ofo re tan, ao da
sinu eko, o di mimu..
*GBOLOHUN RE*
Eyin iyami eleye ooo, ola taka, ola raka, ola
tikanran ragbada, olomo ti nmori oloja merindinlogun, oniyara okiki
igbo, idagirida, idandagiri ti un damo lekun arise kandu, eyin ni onamo
ki iya re o ba sunkun, ako aja aboju meji, abo aja aboju meji, ako aja
aboju merin, abo aja aboju merin, ako aja aboju mejo, abo aja aboju
mejo, ako aja aboju merindinlogun, abo aja aboju merindinlogun, iko ni
ko aja, iko ni ko inaki, eyin iyami eleye ooo, eyin ni e ni abere aye, e lo
fi abere yin gun gbogbo ota mi pa, ki emi ma mo inira mo ooo, ki e wa
lana fun mi ooo, ki un ma rije, ki un ma rimu, ki un ma rina, ki un ma
rilo, ki gbogbo epe lo pa elepe, ki asasi lo pa alasasi, ki ona emi
lagbaja la peregede, afaila ojo, ti ojo ba la ki un la, ito kii bale ko tun
pada senu mo, o di ase, o di imule (Adura).
: *IFERAN OBINRIN ONI OWO PAPER LATI 100 DE 1000*
Ao gbo ewe amunimuye tutu sinu igba kekere kan pelu omin die, ao re owo na sinu re, ti oba di
ojo keji ao to sinu re, ti oba di ojo keta, ao yo owo na, ao sagbe, ao lofun obirin na, tio bati gba
owo na lowo wa tio sina abuse ti buse.
: Ogun ejo
Ao wa isin ti o tila , awalalenu ao ti atare meje bolenu, awe we lowududu ati funfun , awa bomole
fun ojo meje, leyin ojo keje awa wu ninu le ama fi owa wa
: ogun ti ibon ndomi tabi asaki ibon ao wa eyin pepeye tuntun kan ewe eyinolobe tojo ti awu tiditidi
topo die odidi atare nla kan sise re ao fi eyin na tele sinu ape ao yin gbogbo omo inu atare na
lelori ti ikan kogbodo so nu oo ao da ewe na bomole ao jo papo ao lo kunna dada ninu ape nibe
ao fi sin gbere yika ikun wa ao wa fi ebu toku foko elewe kan ninu igba kan lekanna nioo opari
: Ogun ayeeta ibon todaju ao wa obi ifin kan ao ge si (201) obi ipa kan ao ge si (201)eyo atare
(201) eso yanmati (201)oka baba pupa (201) ao wa ko gbogbo re sinu awo oya ao wa dipa pelu
owu dudu ati funfun ao wa se ni apete ao ma fi ara wa jade tabi kia ran mo ara bate na
: Ofo ayeta ibon ao fi erupe ile te ifa eji ogbe si atelewo osi wa pelu eyo atare meta lenu gbolohun
na re erin gbenu igbo fon ni oruko ti anpe iwo ibon,efon gbenu iba fohun loruko ti anpe iwo etu
fanran okun kan soso alaluja loruko ti anpe iwo ota ati ahaya ejiogbe ma je ki akisan meji oba mi
oo bi won bata ni ehin kio male bami ,bi won bata ni egbe mi kio ma le bami ao so be si egbe wa
mejeji ati iwaju ati ehin wa na niooo opari
ELEYI NI IPARA EYONU ATUNDE TODAJU ISEYI KERE AMO IFA NLA NI EPO OBO AO LO
KUN NA AO FITEFA EJIOGBE AO PE OFO SI AO POMO OORI AO MA FI PARA OFORE
AJIROTUTU3* AJIROTUTU NI ALAGBEDE ORUN OHUN LORO FUN ALABAHUN O OR IKOKO
FUN IGBIN ORO EDUN FUN SANGO OHUN NI SANGO FI NLALE LODE ORUN TOFI NBALE
LODE ISALAYE O OR AGOGO IDE FUN AWON IYA MI AJE NI WON FI NPA OMO OLOMO JE
ORUNMILA NI BAWO NI EO SE NI PA OMO OHUN JE WON NI AWON KONI PA
OMO.ORUNMILA JE ORUNMILA NI KIWON JEKI AWON MULE WON NI EPO ERUN DI IMULE
GBOGBO ENITI AWON BATI BA EPO ERUN LARARE TI AWON BATUN FI ENUKAN KI ERUN
RUN AWON TAN TOMOTOMO OORI DI IMULE GBOGBO ENITI AWON BATIBA OORI LARA
RE TI AWON BATUN FI ENU KAN KI AWO KI AWON YO TAN GEREGE BI OORI GBOBO ENITI
AWON BATI BA ERUN LARA RE EYIN KONI BAJE MO.ONI TOHUN TIDI OMO ORUNMILA EMI
L OMO.L MOTIDI OMO.ORUNMILA MOTIFI EPO ERUN PELU OORI SE IMULE KIE MASE DAMI
LAMU KIE SINA OORE FUN MI
*Asiri Ibon Togbona Kerikeri *
*Igbadi re,Ajesinu re,gbere re ati aseje re*
Bamubamu lonki gbogbo pe aku ataro
Gbogbo enikeni eyankeyan tinka atejise bamubamu
Mo pani ase lola asiri ti adaniwaye fi da oju ti efinri ohun ti Taiwo bamubamu ko ka
*Vau mio ni ku iku ojiji*
Bimo se ko yen
Eyina efi enu yin yala be pe
*Vau mio ni ku iku ojiji*
Aiye tawa nisinyi ki onikaluku lo di Ori arare munioo
Ti adaniwaye bansho wa emajeki awa na masho arawa oo
Elomi yio rope ogun ibon toun ti se nigbakan nshi nbe Lara oun laimope ise Ara oun tidi obu,ise
arare ti expire,won o mawa daya ko ibon,emi o mawa se ofo,amo ise eleyi koni expiry date ooo
Bi abanse nwe pelu Omi ni ise ibon eleyi o matun gun oke si,Koda ti wonba nse yinbon luwa ni
ibon na o ma gba idi soro,eyiti o bawa je omo Ogun lakaiye bi tiwa Tori tabati ti pari Asiri yi atidi
omo Ogun lakaiye ti ogun lakaiye o gbodo fi eje re we
Ti eni doju ibon na kowa baje omo Ogun,ibon oun kotie ni fohun rara ni tojepe tobani ki ohun fi
agidi yin,yio subu gbonrangandan sile,iseyi daju ooo
Kama fa Oro gun e tele mi kalo nitori enibalo lobaku gbogbo eniti nka Oro mi oniku iku owowo
*Isenare oo*
Eolore wa Eyin Adiye Ibile meta
Eo wa lowa ewe ehinolobe
Eo Wu idi igi kan re,eowalo kuna dada pelu kuluso kan pelu eyo atare kan
Eo wa su roborobo kekeke sona meta
Eo wa da awon adiye na lu ni eyo kokan,eo wa ju nkan yi diedie sinu eyin na
(Eo wamu garri die,Eo waja ewe ewuro tutu meta ati ewe rinrin die ati ewe bomubomu meta eo
gbo meteta laisi Omi,Omi re laowa gbe kana,eo wada tangiri ni pansa,eo ho inure dada,eo wa ko
ota inu Omi meta (okuta inu odo)
Eo ko bi aro idana sinu tangiri na
Eo wako sakiti ewe ti a gbo yen sinu tangiri na,ti Omi ti a gbo yen batin hooo Lori ina tagbesi yi,eo
wafi Omi yen te eba na,eo fi diedie awon eba yen di oju awon eyin adiye meteta ti e dalu yen,Eba
toba ku,eo gbesi egbekan na,eo sese wako awon eyin adiye meteta na sori awon ota Omi yen inu
tangiri na,Eo waniki Akuwarapa(oni warapa abi abarameji alaboyun abi Aro ti o ro lapa lese bawa
tu ito enure sori awon eyin naa,kosi nnkan tiyio se eyikeyi taba gba ito enure ninu won ooo Eo
wade omori pansa tangiri na,Eo gbesi Ori ina ki ina rora majo si tangiri na
Ti obawa ti se die ti eyin na o tife jina,eo da tangiri na lu nidi,eo gba idi yo awon eyin na pelu ota
Omi meteta na,eo ko awon eyin adiye meteta na losidi igi ope lale,eoma wa ya igbe,eoma je awon
eyin meteta lai ya enu,
Eo wako ako okuta meta yi,eo so ikan fun ope,eo shi epo igi ope na nibiti okuta yen tiba igi ope
na,Eo fi ikeji le Ori igbe ti e ya,eo da yepe bo,eowa mu okuta ota Omi keta,eolofun omo ibeta kan
pelu ohun tiyio dun mo ninu
Eo wa gbe tangiri na sinu ape ijogun,Eo fi Odindi atare kan ti legbe pelu epo igi ope ti ashi yen,Eo
wako ewe ailu lelori,eo wa bere sini jo tebawa jotan eolo kuna dada
Eoda ebu resi meta
Eo fi Ebu alakoko singbere yika ikun wa tiyio jina sirawon, gbere na kogbudo sunmo arawon oo,Eo
fi ebu idakeji foko mu ni ago Kan osan,Eo wa da ebu idaketa sinu orogbo ti apani pansa,eo fi
esinsin kan ati eyo atare kan si,eo de pansa na,eo fisinu owu otutu,eofi eyin adiye obu(eyin ti
adiye fi de ile,tiko pa kan)ti eo wawe ni owu dudu ati funfun,eo wa ran ni igbadi awo eranko
hmmmm to aomaso mo idi, kaikai kiwon gba idi ibon mole lemeta,ki won so aso pupa tiwon ti pari
nkan simo ibon,hmmmm wallahi tallahi raabuli kabah mofi ojo tiyio kumi ku olohun bura,won sere
ni,won ti gbagbe pe eyin obu kinfohun ni
Eba ti awa te ti afisi egbekan yen
Eo fi je obe tiwon bu Omi agbon ti o jabo funrare si die
Abo abi isasun tewa fijehun yen,eo lofi sidi ogun lakaiye
Lobatan patapata
Titi aofidi akolebo ni asiri yi nfi sise Ooo
Amo oni ewoo Oooooo
*N:b*
1. Odi ojo ti ibeta toni arun iru eniti a lo ito enure bayinbon funwa koto lemu wa
2. Ojo taba ma singbere na
Lati eyin niyio ti bere sini sin gbere na,tobato asiko ti o fesin iwaju,ao wa yiju si pelu oju lile(ti
aojeki oju wa le)
3.Besini ojoti eje wa blood wa bayinbon luwa ibon na yio dahun ooo
Amo oun na yio tele wa lojona tori *oko ti aba somo ope lonso funi pada*
3.Eyin obu yen eo gbodo jeki o fo ninu igbadi ti a ran yen
Ojo toba si fo,ojo na lao pa adiye pupa fun,eo wako owo eyo merindinlogun eo la inu akuko adiye
na,eo kosi,eo fisinu isasun olomori,eo bu Omi okun si,eo lo rimole lehin ojo kerindunlogun
eolowu,eoko gbogbo owo eyo yen jade,eo ranmo igbadi na lara kakiri
Ojo ti wonba doju ibon kowa abi lotun losi wahala nsele ibon nsi ro kanrokanro
Ao ko mawipe *Kuluso kuluso Oooooo Abiyamo afi eyin so*
*Lobatan*
*Kosi ayokuro kosi afikun koda awon oni fayawo mi njerisi*
*Professor Taiwo bamubamu*
OGUN_AJEGUN
a o wa egbo tude , erunrun ide , a o gun
mo ose dudu iwe ekan , a o wa gbo ewe
lapamejeji , ewe ewuro tutu , sinu omi , a
o da sakiti re nu , a o wa fi ose yi we omi
yi , a o fi epo para ki ato we , ekan lodun
ni iw
AYETA IBON
AO WA GD OMINNI KAN, AO WA KA Y ATARE 201 NI AO KA, AO WA TO SI GBOGBO ARA GD
YII, AO WA L SI IBI ODO LÁ KAN TABI KI AWA OMI BARIGO IKE NLA TI ALE W INU R TI WN
KONI RI ORI WA RARA, AO WA W INU OMI YN TI ARA WA KO GB D HAN SITA, AO WA MIN GD
YI NI ISALE ODO. LO BA PARI.
Owo moto
Ao wa isawrun 3 omo atare 3 epa yiyn eyo 3 ao jopo ao di n ikobere ao gban awo dudn aomalo
Ogun owo todaju alowa orogbo kan eyo atare meji ao lowa ekisa die aloba obirin su ao fi ekisa ti
Aya ye nu ikan omo kun rin wa ti yo mu dada alosa si abele ti obatigbe ao ge ori orogbo ye Ati idi
re ao gbe ni nu die loke Ati isale ti kogbodo jarawan ao fi mi tare si inu re ao ya aso di e ninu aye
ao fidi bena latise ibeji na awa fi mori de mejeji dada awadi ni ikobere ao maju sapojadelo
owotodajuni
Ogun ajabo to daju
Lili aye kan ao wa fi odidi atere kan si tio di mu ao wa fi okun abo di tio ni han ma rara ao da ma
abe odo fun ojo meta osese ki ama ba lili yan nibe ma kii aba okun nikan tabi kia siba ao wa jo
awa fi sagbere yi po inu wa opo eyan lelo
[10/22, 11:01 PM] +234 706 529 8290: Ogun jinjinni
Ori sebe oka baba odidi atare jijo inu omi rin oko lao ti ma fi foko mu ohun re
Oko loni ki ma koyin lomi inu okaa loni ki ma kayin laya ari tagiri ni t i ejo ori kan ni sebe ni tifi le
igba okunrin.
Ogun ibon todaju
Igbe ewure tio ya loju wa omo atate mesan ao ma omo atare kokan si inu igbe yan kokan ao wa
ma gbemi pelu okele
Ogun ikiya todaju
Esu ti ongbebo dada ao bu die ao lo ao wa ro si inu ibon ao bu omi si eni yio fi foko mu.
Ogun apaji todaju
Igbin apin kan ao lowa ewe ima osun ao wa lo aowa le ma oju igbin yan ao wa gba epo pupa ao
wa bu si oju re ao wa fi odo de male fun ojo meta ti o ba di ojo keta yan ti o ba ku ki eni yan tun
omiran se ti ko ba ku ao wa bo ao walo iyere ma ao fi se ni epo iyo ani je kio tu tu ra ti ao je
OKIGBE IGI TODAMILOJU
Eyin igba ijapa, odindi atare kan, apola igi, ao bu die lara re,
ao jo ninu ikoko titun ni ihoho...
Lilo Re... Ao duro lori odo, ao singbere meje sori, meje is aya, meje
si eyin, ao sin meta si all joint ara wa... gbogbo igi ti won ba lamon
wa koni wole, yio si da sonu...
: Ognu agba ro
Agbo to jabo obi ajopa 3 orogbo gbigbe ati kaka boro 3 ao jopo ao fi sngberr si owo osi
_____________________
Ogun owo moto
Kokoro imu ewure 2atare aja 2 ao jopo mo arigisegi ao wa di n ikobere
Ogun owo ti afi maso nkun todaju
Akuju igbn eyn ope tojabo obi oloju mern 1 kuluso 1 ao jopo adi n ikobere
Agbero
Owo osi oga ao ge ao wa lo wa ewe aluro awa gun papo ao da si ibi ifinmu ao ma fin
Gbolohun re
Ewo Alagemo ki tele ko ro
: FUN ENITI ONFI OJUKO JANKARIWO TESTED aowa oga gbigbe kan ao wafi oga nan ko
jankariwo ti oga nan komi han sitamo aowa jo pelu odidi estate kan ao wafifo ekomu lekan nan
tested
GBETUGBETU TODAJU
IRUN ORI WERE,IYE ETUTU,OWU AKESE PUPA,EYO ATARE MEJE,EDUN ARA,AO LOWON
PAPO AO WAFI AKESE MIRAN NU OJU ARAWA LEYIN TI ABANI IBALOPO TAN,AO WA FI
OWU NA DI EBU TIA LOYE NI IKOBERE AO SOSI KORO IKE BAYAN SORO ODAJU PAA
GBOLOHUN RE:TIGI TOPE NI ETUTU NTU ASO RE FUN,ITUKUTU NI WERE NTU IRUN RE,BI
SANGO BAKE TERU TOMO NIGBA JINIJINI,GBOGBO OHUN TIN BA NSO LONI KIE MASE KO
OHUN ENU MI